FALSE

Page Nav

HIDE
GRID_STYLE
FALSE
TRUE

Latest Update:

latest

Adsense

N'nu Krist' Nikan | In Christ Alone

Authors: Stuart Townend & Keith Getty  N'nu Krist' nikan nireti mi, O'n n'imọlẹ, agbara, orin mi; Igun-ile y...

Authors: Stuart Townend & Keith Getty 
N'nu Krist' nikan nireti mi,
O'n n'imọlẹ, agbara, orin mi;
Igun-ile yii, Apata yii,
Wa sibẹ nin' ọda 'ti'ji.
Ifẹ giga, ibalẹ okan,
'Gbati 'bẹru, idamu pin!
Olutunu, Oun ni mo ni,
Ninu 'fẹ Kristi mo duro.

N'nu Krist' nikan, t'O wa leeyan
Ọlọrun to wa bí ìkókó!
Ẹbun 'fẹ yii at' ododo
T'awọn t'O wa gbala kẹgan:
Lori igi ti Jesu ku,
Irunu Ọlọrun walẹ-
Tori pẹ'ṣẹ wa lo gberu;
Ninu 'ku Kristi ni mo ye.

Nibẹ 'nu 'lẹ l'oku Rẹ wa
Imọlẹ aye t'ookun pa:
Lẹyin eyi lọjọ ologo
O ji dide kuro 'nu oku!
B'O si ti duro n'iṣẹgun
Mo bọ lọwọ egun ẹṣẹ,
Mo jẹ Tirẹ, Oun temi-
Emi ta fẹjẹ Kristi ra.

Niye, niku, ko si 'foya,
Agbara Kristi 'nu mi ni;
Lati 'bẹrẹ titi dopin,
Jesu gba ayanmo mi mu.
Ogun eṣu, ete aye
Ki yoo le gba mi lowo Rẹ,
'Ti y' O fi de, tabi pe mi
N o duro 'nu agbara Kristi.

Translated by Ayọ̀bámi Tèmítọ́pẹ́ Kẹ́hìndé (20/04/2017)
In Christ alone my hope is found,
He is my light, my strength, my song;
this Cornerstone, this solid Ground,
firm through the fiercest drought and storm.
What heights of love, what depths of peace,
when fears are stilled, when strivings cease!
My Comforter, my All in All,
here in the love of Christ I stand.

In Christ alone! who took on flesh
Fulness of God in helpless babe!
This gift of love and righteousness
Scorned by the ones he came to save:
Till on that cross as Jesus died,
The wrath of God was satisfied -
For every sin on Him was laid;
Here in the death of Christ I live.

There in the ground His body lay
Light of the world by darkness slain:
Then bursting forth in glorious Day
Up from the grave he rose again!
And as He stands in victory
Sin's curse has lost its grip on me,
For I am His and He is mine -
Bought with the precious blood of Christ.

No guilt in life, no fear in death,
This is the power of Christ in me;
From life's first cry to final breath.
Jesus commands my destiny.
No power of hell, no scheme of man,
Can ever pluck me from His hand;
Till He returns or calls me home,
Here in the power of Christ I'll stand.

No comments

Youtube Channel