FALSE

Page Nav

HIDE
GRID_STYLE
FALSE
TRUE

Latest Update:

latest

Adsense

Halleluyah! Ogo Ni Fun Baba | Hallelujah! Glory To The Father

Author Unknown  Translated to English by Ayobami Temitope Kehinde Ẹ Jẹ ka jumọ f'ọpẹ f'Ọlorun  Orin iyin, at'ọp...

Author Unknown 
Translated to English by Ayobami Temitope Kehinde

Ẹ Jẹ ka jumọ f'ọpẹ f'Ọlorun 
Orin iyin, at'ọpẹ lo yẹ wa  
Iyanu n'ifẹ Rẹ si gbogbo wa  
Ẹ kọrin 'yin s'  Ọba Olore wa   

Chorus:  
Halleluyah! Ogo ni fun Baba  
A f'ijo ilu yin Ọlọrun wa  
Alaye ni o yin Ọ bo ti yẹ  
Halleluyah! Ogo ni fun Baba   

Ki l'a fi san j'awọn t'iku ti pa?  
Iwọ lo f'ọwọ wọ wa di oni  
'Wọ lo n sọ wa to n gba wa lọw'ewu  
Ẹ kọrin 'yin s'Olutọju wa 
  
Ohun wa ko dun to lati kọrin  
Ẹnu wa ko gboro to fun ọpẹ  
B'awa n'ẹgbẹrun ahọn nikọkan  
Wọn kere ju lati gb'ọla Rẹ ga







Let us give thanks to God together 
Songs of praises and thanks are befitting
Marvelous is Your love to all of us
Oh sing praises to our Gracious King

Chorus:
Hallelujah! Glory to the Father
We praise our God with dances and drums
Only the living will praise you properly 
Hallelujah! Glory to the Father 

How are we better than those who are no more?
It is you that have kept us till today
You keep us and You save us from evil
Sing praises to our Benefactor  

Our voices are not sweet enough to sing
Our mouths are’nt wide enough to give You thanks
Even if we all have a thousand tongues each
They are too small to exalt Your honour. 


No comments

Youtube Channel