Awa Yin O, Olorun Awa njewo Re pe iwo ni oluwa Gbgbo aye fi ori ba le fun o Baba Aye titi lai Iwo ni eniti gbobo awon Angeli Nki gbe pe Orun...
Awa Yin O, Olorun
Awa njewo Re pe iwo ni oluwa
Gbgbo aye fi ori ba le fun o
Baba Aye titi lai
Iwo ni eniti gbobo awon Angeli
Nki gbe pe
Orun ati gbogbo agbara
Ti mbe ninu won
Iwo ni eniti awon Kerubu ati awon Serafu
Kigbe pe ni gba gbogbo pe.
Mimo Mimo Mimo
Oluwa Olorun awon omo ogun
Orun oun aiye
Kun fun ola nla ti o go Re
Egbe awon Aposteli
Ti o logo Yin o
Ogba awon Woli
Ti o dara, Yin o
Ogun awon Matyr
Ti o dara Yin o
Ijo Mimo eniyan Olorun
Ni gbogbo aye Nje wo o Re
Baba en ola nla
Ti Ko ni i pe kun
Ati Omo Re nikansoso
Olo la O lo 'to
Emi Mi mo pelu
Olutunu ni
Kristi, iwo ni Oba Ogo
Iwo ni Omo lailai ti Baba
Nigbati iwo tewogba fun ara Re lati gba eniyan la
O ko korira inu wundia
Nigbati o segun oro iku tan
O si ijoba orun sile fun gbobo
Awon onigbagbo
O jojo ni owo otun Olorun
Ninu Ogo ti Baba
Awa gbagbo pe O mbo wa
Lati se Onidajo wa
Nitorinaa ni awa se ngbadura
Si odo Re
Ran awon omo odo Re lowo
Ti iwo ti fi eje Re
Iyebiye ra pa da
Se won ki a le ka won kun awon eniyan Mimo Re
Ninu ogo Ti ko ni pe kun
Oluwa gba awon eniyan Re la
Ki iwo ki o si fi Ibukun fun awon eniyan i ni Re
J' O ba won
Ki o si ma gbe won leke lailai
Awa ngbe o ga
Ni o jo jumo
Awon si nfi ori bale ni
Oru ko Re
Titi aye ti ko ni pe kun
Fiyesini Oluwa
Lati pa wa mo loni ni ailese
Oluwa Sanu fun wa
Sa a nu fun wa
Oluwa, je ki anu Re ki o ma ba le wa
Gegebi awa ti n gbeke wa le o
Oluwa, Iwo ni mo Gbe ke le,
Lai, ma je kin da mu
No comments