FALSE

Page Nav

HIDE
GRID_STYLE
FALSE
TRUE

Latest Update:

latest

Adsense

Mo F emi Mi Sabe | My Spirit on Thy Care | Yoruba Hymn

1. Mo f’ emi mi sabe Itoju Re Jesu; ‘Wo ko jo mi l’ ainireti, ‘Wo l’ Olorun Ife. 2. ‘Wo ni mo gbekele ‘Wo ni mo f’ara ti: Rere at’ Otit...1. Mo f’ emi mi sabe
Itoju Re Jesu;
‘Wo ko jo mi l’ ainireti,
‘Wo l’ Olorun Ife.
2. ‘Wo ni mo gbekele
‘Wo ni mo f’ara ti:
Rere at’ Otitio ni O,
Eyi t’ O se l’ o to.
3. Ohun t’o wu k’o de,
Ife re ni nwon nse:
Mo f’ ori pamo saiya Re,
Nko foiya iji yi.
4. B’ ibi tab’ ire de,
Y’o dara fun mi sa!
Ki nsa ni O l’ ohun gbogbo,
Ohun gbogbo n’nu Re. Amin.

No comments

Youtube Channel