1. Ninu gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi 'ponju, Abo kan mbe, ti o daju O wa l‘abe ite anu. 2. Ibi kan wa ti Jesu nda ...
Ninu gbogbo igbi 'ponju,
Abo kan mbe, ti o daju
O wa l‘abe ite anu.
2. Ibi kan wa ti Jesu nda
Ororo ayo s‘ori wa;
O dun ju ibi gbogbo lo,
Ite-anu t‘a f‘eje won.
3. Ibi kan wa fun idapo;
Nibi ore npade ore;
L‘airi ‘ra nipa igbagbo,
Nwon y‘ ite-anu kanna ka.
4. A! nibo ni a ba sa si
Nigba ‘danwo at‘ iponju?
A ba se le bori esu
Bo sepe ko si ‘te anu.
5. A! bi idi l‘a fo sibe
B‘enipe aye ko si mo,
Orun wa pade okan wa,
Ogo si bo ite-anu.
Amin.
1. From every stormy wind that blows,
From every swelling tide of woes,
There is a calm, a sure retreat;
‘Tis found beneath the mercy-seat.
2. There is a place where Jesus sheds
The oil of gladness on our heads
A place than all beside more sweet
It is the blood-stain'd mercy-seat.
3. There is a spot where spirits blend,
And friend holds fellowship with friend;
Though sunder'd far, by faith they meet
Around one common mercy-seat.
4. Ah, whither could we flee for aid,
When tempted, desolate, dismay'd?
Or how the hosts of hell defeat,
Had suffering saints no mercy-seat!
5. There, there on eagle wing we soar,
And time and sense seem all no more,
And heaven comes down our souls to greet,
And glory crowns the mercy-seat.
Amen
No comments