1. K ‘ore ofe Krist‘ Oluwa, Ife Baba ail‘opin, Oju rere Emi mimo, K‘o t‘oke ba s‘ori wa; Bayi l‘a le wa n‘irepo Awa ati ...
Ife Baba ail‘opin,
Oju rere Emi mimo,
K‘o t‘oke ba s‘ori wa;
Bayi l‘a le wa n‘irepo
Awa ati Oluwa;
K‘a si le ni ‘dapo didun,
At‘ ayo t‘aye ko ni.
Amin.
1. May the grace of Christ our Saviour,
And the Father's boundless love,
With the Holy Spirit's favour,
Rest upon us from above.
Thus may we abide in union
With each other and the Lord,
And possess, in sweet communion,
Joys which earth cannot afford.
Amen
No comments