FALSE

Page Nav

HIDE
HIDE
GRID_STYLE
FALSE

Featured News

TRUE
HIDE_BLOG

Latest Update:

latest

IWO TO FE WA LA O MA SIN

IWO TO FE WA LA O MA SIN TITI 1. I wo to fe wa la o ma sin titi Oluwa Olore wa Iwo to n so wa n’nu idanwo aye Mimo, logo ola re Bab...

IWO TO FE WA LA O MA SIN TITI
1. I wo to fe wa la o ma sin titi
Oluwa Olore wa
Iwo to n so wa n’nu idanwo aye
Mimo, logo ola re

Baba, iwo l’a o ma sin
Baba, iwo l’a o ma bo
Iwo to fe wa l’a o ma sin titi
Mimo l’ogo ola re.


2. Iwo to nsure s’ohun t’a gbin s’aye
T’aye fi nrohun je o
Awon to mura lati ma s’oto
Won tun nyo n’nu ise re.

3. Iwo to nf’agan lomo to npe ranse
Ninu ola re to ga
Eni t’o ti s’alaileso si dupe
Fun ‘se ogo ola re

4. Eni t’ebi npa le ri ayo ninu
Agbara nla re to ga
Awon to ti nwoju re fun anu
Won tun nyo n’nu ise re.

5. F’alafia re fun ijo re l’aye
K’ore-ofe re ma ga;
k’awon eni tire ko ma yo titi
ninu ogo ise re. Amin.

No comments

YouTube Channel